Nọmba 22:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli OLUWA sì dáhùn pé, “Máa bá àwọn ọkunrin náà lọ, ṣugbọn ohun tí mo bá sọ fún ọ ni kí o sọ.” Balaamu sì bá wọn lọ.

Nọmba 22

Nọmba 22:32-41