Nọmba 22:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaamu dáhùn pé, “Wíwá tí mo wá yìí, èmi kò ní agbára láti sọ ohunkohun bíkòṣe ohun tí OLUWA bá sọ fún mi.”

Nọmba 22

Nọmba 22:34-41