Nọmba 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Heṣiboni ni olú ìlú Sihoni, ọba àwọn ará Amori. Ọba yìí ni ó bá ọba Moabu jà, ó sì gba ilẹ̀ rẹ̀ títí dé odò Arinoni.

Nọmba 21

Nọmba 21:23-35