Nọmba 21:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí èyí ni àwọn akọrin òwe ṣe ń kọrin pé:“Wá sí Heṣiboni!Jẹ́ kí á tẹ ìlú ńlá Sihoni dó,kí á sì fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀.

Nọmba 21

Nọmba 21:17-35