Nọmba 21:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli gba gbogbo ìlú àwọn ará Amori, Heṣiboni ati àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè rẹ̀, wọ́n sì ń gbé inú wọn.

Nọmba 21

Nọmba 21:24-34