Nehemaya 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ̀ ni Baruku, ọmọ Sabai, ṣe àtúnṣe láti apá ibi Igun odi títí dé ẹnu ọ̀nà ilé Eliaṣibu olórí alufaa.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:10-23