Nehemaya 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ̀ ni Eseri ọmọ Jeṣua, aláṣẹ Misipa, náà ṣe àtúnṣe apá kan lára ibi ihamọra ní ibi igun odi.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:15-20