Nehemaya 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn arakunrin rẹ̀ ṣe àtúnṣe agbègbè tiwọn náà: Bafai ọmọ Henadadi, aláṣẹ ìdajì agbègbè Keila ṣe ti agbègbè rẹ̀.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:13-25