Nehemaya 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ̀, Meremoti, ọmọ Uraya, ọmọ Hakosi, ṣe àtúnṣe apá tiwọn láti ẹnu ọ̀nà ilé Eliaṣibu títí dé òpin ilé Eliaṣibu.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:11-30