Nehemaya 13:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ranti, Ọlọrun mi, nítorí pé wọ́n rú òfin àwọn alufaa, wọn kò sì mú ẹ̀jẹ́ àwọn alufaa ati ti àwọn ọmọ Lefi ṣẹ.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:24-31