Nehemaya 13:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn ọmọkunrin Jehoiada, ọmọ Eliaṣibu olórí alufaa, fẹ́ ọmọ Sanbalati ará Horoni kan, nítorí náà mo lé e kúrò lọ́dọ̀ mi.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:20-30