Matiu 28:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lójijì Jesu pàdé wọn, ó kí wọn, ó ní, “Ẹ pẹ̀lẹ́ o!” Wọ́n bá dì mọ́ ọn lẹ́sẹ̀, wọ́n júbà rẹ̀.

Matiu 28

Matiu 28:3-11