Matiu 28:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn obinrin náà bá yára kúrò níbi ibojì náà pẹlu ìbẹ̀rùbojo ati ayọ̀ ńlá, wọ́n sáré lọ sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.

Matiu 28

Matiu 28:6-14