Matiu 28:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wá sọ fún wọn pé, “Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ lọ sọ fún àwọn arakunrin mi pé kí wọ́n lọ sí Galili; níbẹ̀ ni wọn yóo ti rí mi.”

Matiu 28

Matiu 28:8-17