Matiu 20:33-34 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Wọ́n dá a lóhùn pé, “Oluwa, a fẹ́ kí ojú wa là ni.”

34. Àánú wọn ṣe Jesu, ó bá fi ọwọ́ kàn wọ́n lójú. Wọ́n ríran lẹsẹkẹsẹ, wọ́n bá ń tẹ̀lé e.

Matiu 20