Matiu 20:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Àánú wọn ṣe Jesu, ó bá fi ọwọ́ kàn wọ́n lójú. Wọ́n ríran lẹsẹkẹsẹ, wọ́n bá ń tẹ̀lé e.

Matiu 20

Matiu 20:26-34