Matiu 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n súnmọ́ Jerusalẹmu, tí wọ́n dé Bẹtifage ní Òkè Olifi, Jesu rán àwọn ọmọ-ẹ̀yìn meji lọ ṣiwaju.

Matiu 21

Matiu 21:1-9