Matiu 19:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu sọ fún un pé, “Nítorí kí ni o ṣe ń bi mí nípa ohun rere? Ẹni rere kanṣoṣo ni ó wà. Bí o bá fẹ́ wọ inú ìyè, pa àwọn òfin mọ́.”

Matiu 19

Matiu 19:9-26