Matiu 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi Jesu pé, “Òfin bí irú èwo?”Jesu sọ fún un pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ pa eniyan. Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe àgbèrè. Ìwọ kò gbọdọ̀ jalè. Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́rìí èké.

Matiu 19

Matiu 19:8-23