Matiu 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà kan, ẹnìkan wá sọ́dọ̀ Jesu, ó bi í pé, “Olùkọ́ni, nǹkan rere wo ni kí n ṣe kí n lè ní ìyè ainipẹkun?”

Matiu 19

Matiu 19:12-18