Kronika Kinni 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi pàṣẹ pé kí gbogbo àwọn àjèjì tí wọn ń gbé ilẹ̀ Israẹli péjọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí kó wọn ṣiṣẹ́, ara wọn ni wọ́n gbẹ́ òkúta fún kíkọ́ tẹmpili.

Kronika Kinni 22

Kronika Kinni 22:1-8