Kronika Kinni 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà Dafidi pàṣẹ pé, “Ibí yìí ni ilé OLUWA Ọlọrun, ati pẹpẹ ẹbọ sísun yóo wà fún Israẹli.”

Kronika Kinni 22

Kronika Kinni 22:1-9