Kronika Kinni 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Hiramu, ọba Tire kó àwọn òṣìṣẹ́ ranṣẹ sí Dafidi, pẹlu igi kedari ati àwọn ọ̀mọ̀lé ati àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà láti bá a kọ́ ilé rẹ̀.

Kronika Kinni 14

Kronika Kinni 14:1-6