Kronika Kinni 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ṣe akiyesi pé Ọlọrun ti fi ìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Israẹli, ati pé Ọlọrun ti gbé ìjọba òun ga nítorí àwọn ọmọ Israẹli eniyan rẹ̀.

Kronika Kinni 14

Kronika Kinni 14:1-10