Kronika Kinni 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àpótí Majẹmu Ọlọrun náà wà ní ilé Obedi Edomu yìí fún oṣù mẹta, OLUWA sì bukun ilé Obedi Edomu ati gbogbo ohun tí ó ní.

Kronika Kinni 13

Kronika Kinni 13:7-14