Kronika Kinni 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ati àwọn eniyan ń fi tagbára-tagbára jó níwájú Ọlọrun, pẹlu orin ati àwọn ohun èlò orin: dùùrù, hapu, ìlù, Kimbali ati fèrè.

Kronika Kinni 13

Kronika Kinni 13:1-14