Kronika Kinni 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti dé ibi ìpakà Kidoni, àwọn mààlúù tí wọn ń fa kẹ̀kẹ́ náà kọsẹ̀, Usa bá di Àpótí Majẹmu náà mú kí ó má baà ṣubú.

Kronika Kinni 13

Kronika Kinni 13:1-11