Kronika Kinni 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé Àpótí Majẹmu náà jáde láti ilé Abinadabu, wọ́n gbé e lé orí kẹ̀kẹ́ titun. Usa ati Ahio sì ń wa kẹ̀kẹ́ náà.

Kronika Kinni 13

Kronika Kinni 13:6-9