43. Hanani, ọmọ Maaka, ati Joṣafati, ará Mitini;
44. Usaya, ará Aṣiteratu, Ṣama, ati Jeieli, àwọn ọmọ Hotamu, ará Aroeri,
45. Jediaeli, ọmọ Ṣimiri, ati Joha, arakunrin rẹ̀, ará Tisi,
46. Elieli, ará Mahafi, ati Jẹribai, ati Joṣafia, àwọn ọmọ Elinaamu, ati Itima ará Moabu;