Kronika Kinni 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin wọnyi ni wọ́n lọ bá Dafidi ní Sikilagi, nígbà tí ó ń farapamọ́ fún Saulu, ọmọ Kiṣi; wọ́n wà lára àwọn akọni tí wọ́n ń ran Dafidi lọ́wọ́ lójú ogun.

Kronika Kinni 12

Kronika Kinni 12:1-6