Kronika Kinni 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

dípò kí ó bèèrè ìtọ́sọ́nà lọ́wọ́ OLUWA. Nítorí náà, OLUWA pa á, ó sì gbé ìjọba rẹ̀ fún Dafidi, ọmọ Jese.

Kronika Kinni 10

Kronika Kinni 10:10-14