Kronika Kinni 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá parapọ̀, wọ́n wá sọ́dọ̀ Dafidi ní Heburoni, wọ́n ní, “Wò ó, ẹ̀jẹ̀ kan náà ni gbogbo wa pẹlu rẹ.

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:1-11