Kronika Kinni 11:33-37 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Asimafeti, ará Bahurumu, ati Eliaba ará Ṣaaliboni;

34. Haṣemu, ará Gisoni, ati Jonatani, ọmọ Ṣagee, ará Harari;

35. Ahiamu, ọmọ Sakari, ará Harari, ati Elifali, ọmọ Uri;

36. Heferi, ará Mekerati, ati Ahija, ará Peloni;

37. Hesiro, ará Kamẹli, ati Naarai ọmọ Esibai;

Kronika Kinni 11