Kronika Keji 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe tabili mẹ́wàá, ó gbé wọn kalẹ̀ ninu tẹmpili: marun-un ní ìhà gúsù, marun-un yòókù ní ìhà àríwá. Ó sì ṣe ọgọrun-un àwo kòtò wúrà.

Kronika Keji 4

Kronika Keji 4:1-12