Kronika Keji 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ṣe ọ̀pá fìtílà wúrà mẹ́wàá bí àpẹẹrẹ tí wọ́n fún un. Ó gbé wọn kalẹ̀ ninu tẹmpili: marun-un ní ìhà gúsù, marun-un yòókù ní ìhà àríwá.

Kronika Keji 4

Kronika Keji 4:6-11