Kronika Keji 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ gbọ̀ngàn kan fún àwọn alufaa, ati òmíràn tí ó tóbi, ó ṣe ìlẹ̀kùn sí wọn, ó sì yọ́ idẹ bo àwọn ìlẹ̀kùn náà.

Kronika Keji 4

Kronika Keji 4:4-12