Kronika Keji 32:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ati àwọn ará Jerusalẹmu bá rẹ ara wọn sílẹ̀, wọ́n sì ronupiwada. Nítorí náà, OLUWA kò bínú sí wọn mọ́ ní ìgbà ayé Hesekaya.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:19-30