Kronika Keji 32:25 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn Hesekaya ṣe ìgbéraga, kò fi ẹ̀mí ìmoore hàn fún ohun tí Ọlọrun ṣe fún un. Nítorí náà, inú bí OLUWA sí àtòun ati Juda ati Jerusalẹmu.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:24-31