Kronika Keji 32:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ní ọpọlọpọ ọrọ̀ ati ọlá. Ó kọ́ ilé ìṣúra tí ó kó fadaka, ati wúrà, ati òkúta olówó iyebíye, ati turari sí, ati apata ati gbogbo nǹkan olówó iyebíye.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:26-29