Kronika Keji 17:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó ń sin Ọlọrun àwọn baba rẹ̀, ó pa òfin Ọlọrun mọ́, kò sì tẹ̀lé ìṣe àwọn ọmọ Israẹli.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:3-10