Kronika Keji 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wà pẹlu Jehoṣafati nítorí pé ó tẹ̀lé àpẹẹrẹ ìgbà ọ̀dọ̀ Dafidi, baba rẹ̀; kò sì bọ oriṣa Baali.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:1-4