Kronika Keji 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó àwọn ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi Juda, ó yan olórí ogun fún wọn ní ilẹ̀ Juda ati ní ilẹ̀ Efuraimu tí Asa baba rẹ̀ gbà.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:1-3