Kronika Keji 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà OLUWA fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, gbogbo àwọn ọmọ Juda sì ń san owó orí fún un. Nítorí náà ó di ọlọ́rọ̀ ati ọlọ́lá.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:2-14