Kronika Keji 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni dá Ọlọrun lóhùn, ó ní “O ti fi ìfẹ́ ńlá tí kìí yẹ̀ han Dafidi, baba mi, o sì ti fi mí jọba nípò rẹ̀.

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:4-14