Kronika Keji 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, Ọlọrun, mú ìlérí tí o ṣe fún Dafidi, baba mi, ṣẹ nisinsinyii, nítorí pé o ti fi mí jọba lórí àwọn eniyan tí wọ́n pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:8-13