Kronika Keji 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òru ọjọ́ náà, Ọlọrun fara han Solomoni, ó wí fún un pé “Bèèrè ohun tí o bá fẹ́ kí n fún ọ.”

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:3-13