Kọrinti Kinni 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mò ń fi ìyà jẹ ara mi, mò ń kó ara mi ní ìjánu. Ìdí ni pé nígbà tí mo bá ti waasu fún àwọn ẹlòmíràn tán, kí èmi alára má baà di ẹni tí kò ní yege ninu iré-ìje náà.

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:18-27