Kọrinti Kinni 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, ẹ má gbàgbé pé gbogbo àwọn baba wa ni wọ́n wà lábẹ́ ìkùukùu. Gbogbo wọn ni wọ́n la òkun kọjá.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:1-3