Kọrinti Kinni 9:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, aré tí èmi ń sá kì í ṣe ìsákúsàá láìní ète. Èmi kì í máa kan ẹ̀ṣẹ́ tèmi ní ìkànkukàn, bí ẹni tí ń kan afẹ́fẹ́ lásán lẹ́ṣẹ̀ẹ́.

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:21-27