Kọrinti Kinni 9:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gbogbo àwọn tí ń sáré ìje a máa kó ara wọn ní ìjánu. Wọ́n ń ṣe èyí kí wọ́n lè gba adé tí yóo bàjẹ́. Ṣugbọn adé tí kò lè bàjẹ́ ni tiwa.

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:15-27